ondo Aso oke
ondo A*o oke is all about beauty,health and wellness
Situation at the moment at Ondo town Now,The Rain refuse to stop, olorun saanu o ojo Yi po o
29/07/2026
Amin o, Gbogbo wa lo Nilo Alaanu ki olorun ran siwa
29/07/2026
Ondo A*o oke
29/07/2026
Eyin Eniyan mi Ama ku ojo,Se ojo yen de odo yin ,ojo Itura ni yoo je fun Gbogbo wa,E kaaro
Oluranlowo Ti Koni siregun Olorun a Ran Siwa lose Yi.
IRe Ni Tiwa lose Yi
27/07/2026
Gbogbo ise loni wahala ATI idojuko, sugbon bi won bani ki e Yan oko Ninu Awon Arakunrin Yi Tani e maa mu,Ti e rope ise re a fiyin lokan Bale
Mrs Alamu principal to gba ominira Jeri si Agbara Olorun Lana ni Ile ijosin re Gbogbo Awon Eniyan ba dupe,oko ATI Awon omo won jade lati dupe Lowo Gbogbo Eniyan, Olorun a jeki a Maa Leri Ayo
Grateful to God for this new week
27/07/2026
Happy New week To All patronize ONDO A*o oke 09157873192
Click here to claim your Sponsored Listing.
Category
Website
Address
Ondo