Tito TV

Tito TV

Share

A lover of God creating content
l share relatable contents Daily prayers in Yorùbá and English that can help your day by day life journey.

remember the best is yet to come 🙏🏻

27/09/2026

Ìwọ to rí Amin se Ọ̀tá to ní ire yín tomotomo kò ní sojú ohun iná Ọlọ́run kò lù irú ènìyàn bẹẹ láṣẹ Èdùmàrè Àmín

27/09/2026

Amin o Jesu Kristi 🙏🏻

27/09/2026

Amin loruko Jesu Kristi 🙏🏻🙏🏻🙏🏻

27/09/2026

Òni ni ojo isinmi
Ojúmọ́ ayò lo mọ wá lóni o Ire gbogbo wá kò ní kọjá wá a rí Ire ayò gbá lóni láṣẹ Elédùmarè 🙏🏻

26/09/2026

Gbogbo ìwọ to tẹ Amin ilẹkun ohun rere ti Ọ̀tá tí tí mọ ọ láṣẹ Èdùmàrè ilẹkun naa sì fún ayọ iserere rẹ láṣẹ Èdùmàrè Àmín

26/09/2026

OJUMO IRE TO MỌ WÁ
LONÍ Ẹ̀MÍ ÀTI ÌWỌ A NÍ RÍ IBANUJE KÒ NÍ JẸ ÌPÍN GBOGBO WÁ ÌPÈ ỌFỌ A NÍ GBÀ LÁṢẸ ÈDÙMÀRÈ ÀMÍN

25/09/2026

Gbogbo ìwọ abiyamo to rí àdúrà yi àwọn ọmọ rẹ ko ní parẹ mọ ọ lójú láṣẹ Elédùmarè e ní fojú sunkún ọmọ Àmín 🙏🏻

25/09/2026

Gbogbo eyin abiyamo tẹ rí Amin ṣe Ọmọ aráyé ó ní sọ Ọmọ yín di Ọ̀tá yín láṣẹ Elédùmarè Àmín 🙏🏻

25/09/2026

Ògo ní fún Ọlọ́run lókè ọrùn........mo jí layọ bàbà mo dupẹ o🤷‍♂️🤷‍♂️🤷‍♂️

24/09/2026

Ní òru òní ibanuje kò ní Wole Gbogbo wá ẹkún ohun ose kò ní dapo mọ Ayọ Gbogbo ọrùn Ayọ là má su a ní jì sínú wahala àti idamu láṣẹ Èdùmàrè Àmín

Want your business to be the top-listed Beauty Salon in Lagos Harbour?
Click here to claim your Sponsored Listing.

Address


Lagos Harbour
11011