Irawo ati aboyo ninu ishoro
This group is created for enlightenment of humans base on the secret about stars(Irawo) we use in life and steps to take to be successful in life
Salam aleikum warahmotu llahi wabaraka tuhu
blessed morning everyone@all pls can't read many messages but if u need anything u can call through my number 08061518679
Shout out to my newest followers! Excited to have you onboard! Davies Michael, Basiru Ayanfe Oyedotun, Agboola Ariremako, Rebbeca Osunbode, Ola Kamal, Faramade Olatundun, Michael Ojo, Kafayat Mojirade, Adesola Joshua, Adetunji Ayodele, Boyle Fried, Kowope Arole, Comfort Tayo, Ghato Ganiu, Adesoji Lekan, Akinola Ayodele Gabriel, Adeyeye Segun, Adenike Adebayo, Afeez Lawal, Alice Aduke, Abiye Aduni Arigbagba, Badimusi Kabiru, Omo Ola Bread, Opeyemii T Akindunbi, Olabanji Ajewole, Olaiya Ololade, Muftau Abiodun, Toyosi Musibau Oyebamiji, Saka Abdulsalam, Akintunde Alabi, Oladele Temitope, Ayoka Omo Irunmole, Idera Jesun, Adeisa Monday
18/09/2026
let's take this a good night and saying blessed weekend
OGUN AISAN INU GBOGBO TABI INFECTION
Ewe ewuro, Ewe efinrin, Ewe lapa pupa ati ewe ejinrin wewe die.E foo(wash it) ke gboo(squeeze it)pelu iyo die(small salt).
eshe pẹlu àjọ kero sinu ike ragoliz kan
O di mimu kaa to jeun laaro. O dara pupo lasiko nnkan osu obinrin. To ba pari tan to sun mo oko won. A loyun ni osu naa. insha Allah
fún Ọkùnrin laro laro nikan ni mumu rẹ
abawa laramu insha Allah
18/09/2026
agbo jedi, ọpa eyin, ale to daju
Baara kan
Tagiri kan
aoge mejeji yi sí wẹwẹ
Kaun bilala diẹ
alefi
Omi ogi/emu/oronbo/oti ki Lagbo
leyin ojo keta odi mumu laro laro
yíò bawa laromu insha Allah
you can call or message on Whatsapp
08061518679
for spiritual findings or about ur star(irawo)
but pls always indicate u are from this group
let's try this again
have been many chat asking about why no post all this while very sorry been busy thats y
*🥳ISORA/AGBELEPOTA TO DAJU-GAN*
🥳ORI AWONRIWON KAN
PATAKO ESIN
ISU OGIRISAKO
ODIDI ATARE
KAN
AO JO PAPO AO LO AO RO SINU ADO ATO KAN, AO MABU DIE
SOWO PE OHUNRE....
EJIOGBE NI IFARE.....
*🗣OHUNRE*....
ORI NI AWONRINWON NI TIFIPE LAIYE, OKO NI AGBE NFI ISU
OGIRISAKO SIDI EEMI, KUTAKURA-KUTAKURA AIYE NIFI ILE SILO, KI
GBOGBO AWON OTAMI, KI WON FIMI SILE S'AIYE
LO, EMI.....OMO..... NI KIN REYIN AWON OTAMI.... ADUA ....AO LA
AO MAFI OMI LO Abi Eko tutu laro laro ..HMMMM......
ISE NIO EBAMI DANWO
18/09/2026
Salam aleikum warahmotu llahi wabaraka tuhu
is been long
hope everything is going well
may Allah bless us with greatness in life
ND happy blessed Friday
ASIRI BIBO TIPATIPA TI AFI RI OWO GBA LỌWỌ CLIENTS WA..
ẸYỌNU A
TUDE
ASINA
.......
Epo obo die
Ewe ewuro 16
Ike funfun olomori
Oyin gidi
Ose dudu tabi eyikeyi ose ti o ba wunwa
Aogun epo obo yii,aowa dapapo pelu ewe ewuro 16,ao wa gun mejeji papo tio kunna,aowa po papo pelu eyikeyi ose daada,
ao wa sẹsẹ daa oyin sibi 3 lati po ose yii papo,
aowa ko sinu ike funfun olomori ao de pa Di ojo keji
Odi wiwẹ
IKILO PATAKI:
Alale nikan ni a le we ose yii.
Ao gbọdọ we ose yii ni awon ojo meji yii,
Ale
Wednesday and Saturday
Salam aleikum
Is been long
What can we talk about
Is December period
Let's watch out
*let's use this a long time greetings BTN ourselves
ASEJE ASINA*
Ewe orijin ao lo po mọn ata ìjọsìn mesan ao fi se igbin je ni epo ni iyo
*ASEJE OWO*
Ewe gure ewe onitikuti ewe sawerepepe ewe Igbo ao lo po mọn ata ìjọsìn mesèn ao fi se eyin adire agiriki merin je ni epo ni iyo
*ASEJE OWO*
Ewé àjé ewe sawerepepe ewe Igbo ao lopo mọn ata ìjọsìn mesèn ao fi se akuko adire kan je ao ge sí 16 ao sè ni epo ni iyo
*ASEJE OWO*
Ẹjẹ arọ kan ao gesi meta ao ni geja o ao wa lo ra ẹyẹ onbe mẹta ao lo po mọn ata ìjọsìn mesan ao fi se ẹjẹ arọ na je ni epo ni iyo
*ASEJE OWO*
Omudun ewe ipin mẹsan omudun ewe lapa funfun mesan ao lopo mọn iyere mesan ao fi po eyin agiriki meta ao ro sí inú ọra kan sọ se ti oba jina ao fi ipepe ge eyin yẹn sí mẹta ao se adura sí ao je
*ASEJE OWO*
Eyin pẹpeye meta ao kò sí inú isasun ao dà omi agbani sí ao fi se jena ao jeki omi yẹn gbe mọn lara ao se adura sí ao je
*ASEJE OWO*
Igbin eyo kan ao ge sí 80 itana sawerepepe 80 itana tanapowo 80 ao lo po mọn ata ìjọsìn ao fi se igbin yen je ni epo ni iyo
*ASEJE OWO*
Iṣu idi tanapowo ao lo pomon iyere mesan ao fi se adire akuko kan je ao ge sí 16 ao fi iru sí
*ASEJE OWO*
Ewe bomubomu 16 ao ko meje tele inu isasun ao ko eyin agiriki merin le ni ori ao ko ewe yẹn mesan le ni ori ao gbé ka iná ao ni bù omi sí óò yíò jina fún rare ti oba jina ao ko ewe yẹn kuro ao je eyin yé ao wa gun epo eyin yẹn mọn ọsẹ ati ewe yẹn ao mọn fi wẹ
*ASEJE OWO*
Egbo iyipo ola ao lopo mọn ata ìjọsìn mesan ao fi se eren ewùrà ekiri mesan je pelu ata ìjọsìn mesan ao se ni epo ni iyo
*ASEJE OWO*
Ekiri ẹran malu mesan ewe sawerepepe ewe aje ao lopo mọn iyere mesan ao se ni epo ni iyo
*ASEJE OWO*
Onbe mẹta ao lopo mọn ata ìjọsìn mesan ao fi se abo adira dudu je ao ge sí 16 ti obe na bajina ao gbé sí orí ibi to ba gan ao jo kò ni ori apoti ao gbé esane wa me ibikan to ri ese wa ko gbodo kan ile ti u be aba je obe yi lowo ao se adura sí dada ao je ale ni ao je obe yi ooo..
Click here to claim your Sponsored Listing.
Category
Contact the business
Telephone
Website
Address
Ita Elepa Agaka Ilorin
Ilorin
Alerts
Be the first to know and let us send you an email when Irawo ati aboyo ninu ishoro posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.