ALFA TAPA
Spiritual problems Solution and so on
09/06/2026
AWURE ANU
Ewe ogbe akuko
Ewe omisinmisin onitakun
Oyin gidi die
Sugar oni koro die
Ose dudu
Ao gun gbogbo re papo
Ao ma fi we pelu adura
ALAFA TAPA HATAPAWI
08124002628
08107555203
EBE AWON AGBA
Fun awon ti irin ajo won daru latari awon agbalagba @
ASEJE OWO NI K IAKIA
TAPA
05/06/2026
AWURE OWO KIAKIA
Ewe abo
Ewe alo
Ewe odan towa larin oja
Ori aparo
Ao gun gbogbo re pelu ose
GBOLOHUN RE
Odan loni kie fi ohun rere dan mi wo,
Alo loni kie fi ohun rere lo mi wo,
Abo ni bo oloja loju ti nfi fi ohun owo re tore
Muwa muwa laparo nke.
Ao se adura si, ao mafi we
ALFA TAPA HATAPAWI
08124002628
08107555203
Help me share it and like 👍
20/05/2026
OBINRIN TIN YA ALE
OBINRIN TI N DOKO TABI OBINRIN TI N YAN ALE
igbe adie ori aba
Asa ibile ti won ma fin
Ori
Ao po gbogbo re papo sinu ike kekere olomori
Okunrin yio ma fi pa nkan omokunrin re, yio ma fi ba iyawo re sun
PELU OGO OLOHUN OBINRIN NA KO NI YAN ALE MO
ALFATAPA
08124002628
08107555203
27/03/2026
EBE AWON AGBA
Ewe imi esu
Odidi atare
Ao jopo, ao lo kunna
Ao po mo ori tabi epo pupa
Ao ma fi para
ALAFA TAPA
08124002628
08107555203
EYONU TI OMO ARAYE FI YONU SIWA
ISOYE
OHUN SISE FUN OMODE ATI AGBALAGBA TI WON MA N GBAGBE OHUN TI WON KO WON NI ILE IWE TABI ILE KEWU, TABI GBOGBO NKAN TI A BA KO @
Click here to claim your Sponsored Listing.
Category
Contact the business
Telephone
Website
Address
Ibadan