Dr. Nohu herbal
specialist on prostate enlargement/UTI/STDs and spiritual problems
06/09/2026
iseto (Urine Retention)
seto seto je ipenija nigba ti apo ito ko le tu gbogbo ito jade, ito wa ti o ku ninu re leyin ti o ba ti to.
ti eniyan ba ni ipenija seto seto awon amin ti o monri ni, ito ti o lora, ito afi Ipa mu, imolara pe apo ito kin si leyin to ba to tan,Tito nigbogbo Igba sugbon die ni o mon jade, Dide ni ale lati to bi emeta ki ile to mon, irora ni isale ikun
kinni monfa isoro seto seto
larin awon okunrin ni aisan yi posi
* arun Akoran
* ojo ori
* apoju eran jije
ki nidi to ye ki a fi toju isoro seto seto
* akoran inu ito Le waye
* nitori kidirin
* Apo ile ito le baje
ti ako ba to ju re boseto ati boseye, to ba gbodi lara ise abe ni ona abayo abi ki eniyan mon fi roba oyinbo to.
kinni ona abayo gbiyanju ko lo si ile iwosan fun ayewo ara
basele to ju re, elobami wa
- ewe areyinkosun tutu
- omikan tabi emu
bawo ni aose se
tabari emu aogbo ewe areyinkosun si inu emu na, to jasi wipe omikan ni ari aose pelu ewe areyinkosun yi ati Aidon ti yio jinna dada
lilore
ilaji cup ni aro ati ni ale.
yio ba ara mun pelu ashe olorun oba
bami like re
comment
share re fun anfani opolopo eniyan
adura wa yi o gba amin.
04/09/2026
iwosan arun egungun (arthritis)
arun egungun abi ka pe ni irora egungun o je arun to ma damu opolopo ni ibi ti egungun meji ba ti pade, bi orun owo, orun ese, ori ikunle ati ibadi, be si ni eyin riro
arun yi a ma waye nigba ti ojo ori (age) bati di agba, oun ni arun yi se po larin awon arugbo wa
* awon apeere ti o ma ri
- Irora ninu egungun
- ki ati dide soke ko je ini ra
- ati duro dede ama je ini ra
- ki ati rin si ini kan bo si ini kan ko je ini ra
- ni ibi ti egungun meji ba ti pade ama dun (sound)
* ki ni o n fa arun riro egungun
- ojo ori
- ti eniyan ba sonra
- aisan ara
- abimon
* bawo ni asele se iwosan re
elobami wa awon nkan ti mo fe ka sile yi
- ewe gova
- ewe opa run
- eru alamon
ao wa awon nkan wonyi tio po die ti won ko ni ju arawon lo, ao se (boiled) ti yio jinna dada
* lilore
ilaji cup kan ni aro, osan ati ni ale
pelu ashe olorun oba yio ba ara mu.
adura wa yio gba, asi ni fi aisan/arun logba amin
ebami share fun anfani elomiran
03/09/2026
Iba apoju ponto je aisan iba ti o wopo ninu aisan iba, aisan iba aponju ponto ama bere nigba ti kokoro malaria ba wa ninu eje, eniyan ti kokoro malaria ba si ti wa ni ara re, yio ma ri wipe Ara gbigbona yio bere besini ara re yio tun bere si ni gbon ati otutu pelu oogun ni ara papa julo ito na yio bere si ni pon.
Awon apeere miiran bi
- Ori fifo
- Irora ara ati egungun
- inu rirun
- Ailera
Ti eniyan ba ti ri awon amin wonyi ki eniyan tete moju to koto di oun ti agbara koni le ka mon,
Lati le segun abi ki adena re, elobami wa awon nkan wonyi
- Egbo egbesi
- Alubosa elewe
- Egbo ipeta
- Egbo ope
- Ewe ibepe
- Ewe ipin
Gbogbo nkan wonyi ni aose ti yio jinna dada.
lilore eniti aisan iba yi ba ti wo lara pupo yio mon mun ilaji cup kan ni aro, osan ati ni ale.
bami share re fun anfani elomiran.
gbogbo wa o ni fi aisan logba pelu ase olorun oba amin.
03/09/2026
Iwosan fun ogbe inu (ulcer)
Egbo inu ni gbigbe tabi ogbe ti o ba waye ninu odi inu tabi inu ifun kekere.
* Ki ni o n fa egbo Inu ti amon si "ulcer" iwadi imon ijinle je ka mon wipe
- Kokoro kan be to Mon gbe inu ti oloyinbo a ma pe ni H pilori
- Oti ati Mimu Siga ole fa isoro ogbe inu
- Ounje ata ati ora ole mu ki isoro ogbe inu koposi
- Irora ni opo Igba ni apa oke inu, papa julo ni Igba ti ebi ba n pa eniyan
- Asilo Ogun a ma fa ni opo Igba
* bawo ni ase le segun arun ogbe inu
Elobami wa awon ewe ti akasile
* ewe ogbo
* ewe lapa funfun
* ewe lapa pupa
bawo ni aose se
ao gbo awon ewe yi papo tio Omi re yio ki dada, leyin re ni ase (filter).
lilore ao Mon yo Omi re si ibikan dede ilaji cup pelu miliki gberefu (milk powder)
* ilaji cup ni aro ati ni ale.
bakana Sora fun awon ikilo wonyi
- Sora fun awon Ogun ti o ye kio lo lai ti je ounje
- Sora fun Siga ati oti mimun
- ma jehun ni asiko
- bakana sora lilo soke lo s**o
Awon ounjẹ ti o dara lati monje fun eni to bati ni ipenija ogbe inu
* Epa * ogede pipon * Efo *wara *Omi pupo
Awon ounje ti eni to ba ti ni ipenija ti o ye ki o sa fun
Ata, kofi, oti, ora ati ohun mimu to ba ni gaasi
yio ba ara mun ni ase olorun oba amin
bami share re fun anfani elomiran
02/09/2026
Iba Taifod (typhoid)
Iba tifoidi (typhoid) abi ka pe ni Arun taifodi, o je Arun akoran ti Kokoro aranka. A ma n gba Arun yi nipa jije ounje tabi mimu omi ti ko mo, tabi nipase olutoju ti o ni arun na.
apeere Arun yi ni ara
* iba yi o ma damu ara ni gbogbo asale diedie
* Ori fifo
* Ailera ati irewesi
* Ara riro
* Aife ounje
bawo ni aose mon wipe arun yi wa ni ara ao se idanwo eje ni ao fi mon.
bawo ni asele dabo bo ara wa lati le mon ni Arun iba taifodi
- Mun omi tomon
- Mon fo owo re ni gbogbo asiko papa julo ti a ba fe je ounje.
- Gbiyanju ko ma je ounje to ba gbona
- Sora fun eso tiwon ti ge ni opopona
bawo ni ase le se iwosan abi idena arun tifoidi, elobami wa awon ewe wonyi
* Ewe tea
* Ewe dongo yaro
* Ewe agunmoni iye
* Ewe gofa
* Ewe mango
* Ewe ibepe
* pineapple
bawo ni aose se
gbogbo awon nkan wonyi ao ko si inu Koko kan leyin Igba ti a ba ti fonu, aose ti yio jinna dada ti yio fi di agbo.
lilore
ilaji cup kan ni aro ati ni ale
gbiyanju kose agbo yi
kodi igba ti Arun iba taifodi ba bere ni ara,
adura wa yio gba pelu ase olorun oba amin.
bami like page wa
bami share alaye iwonsan yi fun elomiran.
iree ooo
Lati dena ito suga
Ose fun Kokoro ara
31/08/2026
lati dena arun ito sugar (diabetes)
Nigbati ara eniyan ba ti wa ni ipo ti ara kole se akoso suga abi glucose to wa ninu eje daradara ti arun ito suga bati wa ni ara ama se ara bi, ki eniyan ko je ounje, ki ounje na yi pada si suga ninu eje.
Apere ti eniyan yio fi mon wipe arun ito sugar ti wa lara ohun
* Oyi Oju
* Ki eniyan mamu Omi ni gbogbo igba
* Ara yio mon ko irewesi
* Ito atoju papa julo ni oru
* Ki eniyan monru ni aimodi
* Ki Oju Egbo mon san
lati dena arun ito suga elobami wa nkan meji yi
- ewe monriga
- ata ile
bawo ni aose se: ao wa ewe moringa tio po die ati ata ile (ginger) ao ko si inu Koko kan ao se ni agbo.
lilore: ilaji cup ni aro ati ni ale
Yio ba ara mun
Ebami like e
Ebami share re fun anfani elomiran
30/08/2026
ose Kokoro ara
kokoro ara je iyipada ti o waye ni awo ara, to jasi wipe ara koni se ri ti orisirisi Kokoro, ela, abi ki ara di koko abi ko pon, baka na Kokoro ara yi na le fa ki eran aran yi (thick)
lati fi le segun abi dena arun kokoro ara
Elo bami wa awon nkan elo yi
- ero alamon
- enu opiye
- imin ojo
- Ose dudu
bawo ni aose se
ero alamon, enu opiye ati imin ojo ao jo papo ninu ikoko kan to ba Jo tan ao lo ti yio kunna dada, ao yi mon ose dudu.
ose dudu yi ni ao mon fiwe ni gbogbo igba
pelu ashe olorun oba ayipade rere yio na awo ara re
adua wa yio gba
Bami like
Bami share re fun anfani elomiran
29/08/2026
ogun ara yiyun (pt 1)
fun eyikeyi ara yiyun, opolopo eniyan ni ara yiyun ti se adoju ti fun ni ori irin abi ni awujo, ara yiyun je nkan ti o da, nigba miiran opolopo Igba ni ara yiyun yi ama fa ki ara mon le ati egbo ni ara to jasi wipe opolopo eniyan won le bo aso ni awujo.
amon lati fi dena ati segun ara yiyun elobami wa
- omi igbin
- Omi agbon
- eyin ororo odidi kan
bawo ni aose se, ao da awon Omi ti agba jade yi si inu ike kan, ao pa gbogbo e papo.
lilore ao mon fi para bi ogbon iseju Kato we
adura wa yio gba amin